ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 8:47
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 tí wọ́n bá ro inú ara wọn wò ní ilẹ̀ tí wọ́n kó wọn lẹ́rú lọ,+ tí wọ́n pa dà sọ́dọ̀ rẹ,+ tí wọ́n sì bẹ̀bẹ̀ pé kí o ṣojú rere sí àwọn ní ilẹ̀ àwọn tó mú wọn lẹ́rú,+ tí wọ́n sọ pé, ‘A ti ṣẹ̀, a sì ti ṣàṣìṣe; a ti ṣe ohun búburú,’+

  • Nehemáyà 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́ tí ẹ bá pa dà sọ́dọ̀ mi, tí ẹ pa àwọn àṣẹ mi mọ́, tí ẹ sì tẹ̀ lé wọn, kódà tí àwọn èèyàn yín tí a fọ́n ká bá wà ní ìpẹ̀kun ọ̀run, màá kó wọn jọ+ láti ibẹ̀, màá sì mú wọn wá sí ibi tí mo ti yàn pé kí orúkọ mi máa wà.’+

  • Ìsíkíẹ́lì 18:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Tó bá sì wá mọ̀, tó sì yí pa dà kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tó ti dá, ó dájú pé yóò máa wà láàyè. Kò ní kú.

  • Jóẹ́lì 2:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọkàn yín ni kí ẹ fà ya,+ kì í ṣe ẹ̀wù yín,+

      Kí ẹ sì pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run yín,

      Torí ó ń gba tẹni rò,* ó jẹ́ aláàánú, kì í tètè bínú,+ ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀ gidigidi,+

      Òun yóò sì pèrò dà* nípa àjálù náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́