Àìsáyà 55:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+ 1 Jòhánù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+
7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+
9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+