Jóṣúà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jóṣúà ọmọ Núnì wá rán ọkùnrin méjì jáde ní bòókẹ́lẹ́ láti Ṣítímù,+ pé kí wọ́n lọ ṣe amí. Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ yẹ ilẹ̀ náà wò, pàápàá ilẹ̀ Jẹ́ríkò.” Torí náà, wọ́n lọ, wọ́n dé ilé aṣẹ́wó kan tó ń jẹ́ Ráhábù,+ wọ́n sì dúró sí ibẹ̀. Mátíù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+Óbédì bí Jésè;+ Hébérù 11:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ìgbàgbọ́ Ráhábù aṣẹ́wó kò jẹ́ kó ṣègbé pẹ̀lú àwọn tó ṣàìgbọràn, torí ó gba àwọn amí náà tọwọ́tẹsẹ̀.+
2 Jóṣúà ọmọ Núnì wá rán ọkùnrin méjì jáde ní bòókẹ́lẹ́ láti Ṣítímù,+ pé kí wọ́n lọ ṣe amí. Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ yẹ ilẹ̀ náà wò, pàápàá ilẹ̀ Jẹ́ríkò.” Torí náà, wọ́n lọ, wọ́n dé ilé aṣẹ́wó kan tó ń jẹ́ Ráhábù,+ wọ́n sì dúró sí ibẹ̀.
5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+Óbédì bí Jésè;+ Hébérù 11:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ìgbàgbọ́ Ráhábù aṣẹ́wó kò jẹ́ kó ṣègbé pẹ̀lú àwọn tó ṣàìgbọràn, torí ó gba àwọn amí náà tọwọ́tẹsẹ̀.+
31 Ìgbàgbọ́ Ráhábù aṣẹ́wó kò jẹ́ kó ṣègbé pẹ̀lú àwọn tó ṣàìgbọràn, torí ó gba àwọn amí náà tọwọ́tẹsẹ̀.+