Jóṣúà 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí ẹ pa ìlú náà run àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀;+ Jèhófà ló ni gbogbo rẹ̀. Ráhábù+ aṣẹ́wó nìkan ni kí ẹ dá ẹ̀mí rẹ̀ sí, òun àti gbogbo àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ilé, torí ó fi àwọn tí a rán níṣẹ́ pa mọ́.+
17 Kí ẹ pa ìlú náà run àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀;+ Jèhófà ló ni gbogbo rẹ̀. Ráhábù+ aṣẹ́wó nìkan ni kí ẹ dá ẹ̀mí rẹ̀ sí, òun àti gbogbo àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ilé, torí ó fi àwọn tí a rán níṣẹ́ pa mọ́.+