Òwe 16:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Orí itan ni à ń ṣẹ́ kèké lé,+Àmọ́ ọ̀dọ̀ Jèhófà ni gbogbo ìpinnu tí ó bá ṣe ti wá.+ Ìṣe 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́ Pétérù sọ pé: “Ananáyà, kí ló dé tí Sátánì fi kì ọ́ láyà láti parọ́ + fún ẹ̀mí mímọ́,+ tí o fi yọ lára owó ilẹ̀ náà pa mọ́?
3 Àmọ́ Pétérù sọ pé: “Ananáyà, kí ló dé tí Sátánì fi kì ọ́ láyà láti parọ́ + fún ẹ̀mí mímọ́,+ tí o fi yọ lára owó ilẹ̀ náà pa mọ́?