Diutarónómì 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 o ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù wọn.+ Rán ara rẹ létí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sí Fáráò àti gbogbo Íjíbítì,+ Diutarónómì 31:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà ló ń lọ níwájú rẹ, ó sì máa wà pẹ̀lú rẹ.+ Kò ní pa ọ́ tì, kò sì ní fi ọ́ sílẹ̀. Má bẹ̀rù, má sì jáyà.”+ Jóṣúà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+ Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+
18 o ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù wọn.+ Rán ara rẹ létí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sí Fáráò àti gbogbo Íjíbítì,+
8 Jèhófà ló ń lọ níwájú rẹ, ó sì máa wà pẹ̀lú rẹ.+ Kò ní pa ọ́ tì, kò sì ní fi ọ́ sílẹ̀. Má bẹ̀rù, má sì jáyà.”+
9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+