-
Jóṣúà 8:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jóṣúà àti gbogbo ọkùnrin ogun wá lọ bá ìlú Áì jà. Jóṣúà yan àwọn jagunjagun tó lákíkanjú tí iye wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n (30,000), ó sì ní kí wọ́n lọ ní òru.
-