Diutarónómì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá mú ọ dé ilẹ̀ tó máa di tìrẹ, kí o súre* ní Òkè Gérísímù, kí o sì gégùn-ún ní Òkè Ébálì.+ Diutarónómì 27:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Tí ẹ bá ti sọdá Jọ́dánì, kí ẹ to àwọn òkúta yìí sórí Òkè Ébálì,+ kí ẹ sì rẹ́ ẹ,* bí mo ṣe ń pa á láṣẹ fún yín lónìí. 5 Kí ẹ tún mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, òkúta ni kí ẹ fi mọ ọ́n. Ẹ má fi irin gbẹ́ ẹ.+
29 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá mú ọ dé ilẹ̀ tó máa di tìrẹ, kí o súre* ní Òkè Gérísímù, kí o sì gégùn-ún ní Òkè Ébálì.+
4 Tí ẹ bá ti sọdá Jọ́dánì, kí ẹ to àwọn òkúta yìí sórí Òkè Ébálì,+ kí ẹ sì rẹ́ ẹ,* bí mo ṣe ń pa á láṣẹ fún yín lónìí. 5 Kí ẹ tún mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, òkúta ni kí ẹ fi mọ ọ́n. Ẹ má fi irin gbẹ́ ẹ.+