Jóṣúà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ẹ̀rù bà á gidigidi,+ torí pé ìlú ńlá ni Gíbíónì, ó dà bí ọ̀kan lára àwọn ìlú ọba. Ó tóbi ju ìlú Áì lọ,+ jagunjagun sì ni gbogbo àwọn ọkùnrin ibẹ̀. Jóṣúà 11:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kò sí ìlú kankan tó bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rẹ́ àfi àwọn Hífì tó ń gbé ní Gíbíónì.+ Gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n bá jà tí wọ́n sì ṣẹ́gun wọn.+
2 ẹ̀rù bà á gidigidi,+ torí pé ìlú ńlá ni Gíbíónì, ó dà bí ọ̀kan lára àwọn ìlú ọba. Ó tóbi ju ìlú Áì lọ,+ jagunjagun sì ni gbogbo àwọn ọkùnrin ibẹ̀.
19 Kò sí ìlú kankan tó bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rẹ́ àfi àwọn Hífì tó ń gbé ní Gíbíónì.+ Gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n bá jà tí wọ́n sì ṣẹ́gun wọn.+