Jóṣúà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sọ fún àwọn Hífì+ pé: “Bóyá tòsí wa lẹ tiẹ̀ ń gbé. Báwo la ṣe máa bá yín dá májẹ̀mú?”+ Jóṣúà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jóṣúà bá wọn ṣàdéhùn àlàáfíà,+ ó sì bá wọn dá májẹ̀mú pé òun máa dá ẹ̀mí wọn sí, ohun tí àwọn ìjòyè àpéjọ náà sì búra fún wọn nìyẹn.+
7 Àmọ́ àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sọ fún àwọn Hífì+ pé: “Bóyá tòsí wa lẹ tiẹ̀ ń gbé. Báwo la ṣe máa bá yín dá májẹ̀mú?”+
15 Jóṣúà bá wọn ṣàdéhùn àlàáfíà,+ ó sì bá wọn dá májẹ̀mú pé òun máa dá ẹ̀mí wọn sí, ohun tí àwọn ìjòyè àpéjọ náà sì búra fún wọn nìyẹn.+