Diutarónómì 20:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Tí o bá sún mọ́ ìlú kan láti bá a jà, kí o fi ọ̀rọ̀ àlàáfíà ránṣẹ́ sí i.+ 11 Tó bá fún ọ lésì àlàáfíà, tó sì ṣí ọ̀nà fún ọ, gbogbo èèyàn tí o bá rí níbẹ̀ máa di tìẹ, wàá máa kó wọn ṣiṣẹ́, wọ́n á sì máa sìn ọ́.+
10 “Tí o bá sún mọ́ ìlú kan láti bá a jà, kí o fi ọ̀rọ̀ àlàáfíà ránṣẹ́ sí i.+ 11 Tó bá fún ọ lésì àlàáfíà, tó sì ṣí ọ̀nà fún ọ, gbogbo èèyàn tí o bá rí níbẹ̀ máa di tìẹ, wàá máa kó wọn ṣiṣẹ́, wọ́n á sì máa sìn ọ́.+