Jóṣúà 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n fèsì pé: Ọ̀nà tó jìn gan-an ni àwa ìránṣẹ́ rẹ ti wá,+ torí a gbọ́ nípa orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, òkìkí rẹ̀ kàn dé ọ̀dọ̀ wa, a sì ti gbọ́ nípa gbogbo ohun tó ṣe ní Íjíbítì+ Jóṣúà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jóṣúà bá wọn ṣàdéhùn àlàáfíà,+ ó sì bá wọn dá májẹ̀mú pé òun máa dá ẹ̀mí wọn sí, ohun tí àwọn ìjòyè àpéjọ náà sì búra fún wọn nìyẹn.+ Jóṣúà 11:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kò sí ìlú kankan tó bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rẹ́ àfi àwọn Hífì tó ń gbé ní Gíbíónì.+ Gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n bá jà tí wọ́n sì ṣẹ́gun wọn.+
9 Wọ́n fèsì pé: Ọ̀nà tó jìn gan-an ni àwa ìránṣẹ́ rẹ ti wá,+ torí a gbọ́ nípa orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, òkìkí rẹ̀ kàn dé ọ̀dọ̀ wa, a sì ti gbọ́ nípa gbogbo ohun tó ṣe ní Íjíbítì+
15 Jóṣúà bá wọn ṣàdéhùn àlàáfíà,+ ó sì bá wọn dá májẹ̀mú pé òun máa dá ẹ̀mí wọn sí, ohun tí àwọn ìjòyè àpéjọ náà sì búra fún wọn nìyẹn.+
19 Kò sí ìlú kankan tó bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rẹ́ àfi àwọn Hífì tó ń gbé ní Gíbíónì.+ Gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n bá jà tí wọ́n sì ṣẹ́gun wọn.+