-
2 Àwọn Ọba 20:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Hẹsikáyà sọ pé: “Ó rọrùn fún òjìji láti lọ síwájú ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá, àmọ́ kì í ṣe bíi pé kò pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá.”
-
-
Sáàmù 135:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Jèhófà ń ṣe gbogbo ohun tó bá fẹ́+
Ní ọ̀run àti ní ayé, nínú òkun àti nínú gbogbo ibú omi.
-