- 
	                        
            
            Jóṣúà 10:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 Lọ́jọ́ tí Jèhófà ṣẹ́gun àwọn Ámórì níṣojú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ìgbà yẹn ni Jóṣúà sọ fún Jèhófà níṣojú Ísírẹ́lì pé: 13 Bí oòrùn ṣe dúró sójú kan nìyẹn, òṣùpá ò sì kúrò títí orílẹ̀-èdè náà fi gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀. Ṣebí wọ́n kọ ọ́ sínú ìwé Jáṣárì?+ Oòrùn dúró sójú kan ní àárín ojú ọ̀run, kò sì tètè wọ̀ fún nǹkan bí odindi ọjọ́ kan. 
 
-