Jóṣúà 21:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Bákan náà, Jèhófà fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo àyíká wọn, bó ṣe búra fún àwọn baba ńlá wọn,+ ìkankan nínú àwọn ọ̀tá wọn ò sì lè dojú kọ wọ́n.+ Jèhófà fi gbogbo ọ̀tá wọn lé wọn lọ́wọ́.+
44 Bákan náà, Jèhófà fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo àyíká wọn, bó ṣe búra fún àwọn baba ńlá wọn,+ ìkankan nínú àwọn ọ̀tá wọn ò sì lè dojú kọ wọ́n.+ Jèhófà fi gbogbo ọ̀tá wọn lé wọn lọ́wọ́.+