ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 33:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó sọ pé: “Èmi fúnra mi* yóò bá ọ lọ,+ màá sì fún ọ ní ìsinmi.”+

  • Diutarónómì 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Tí ẹ bá ti sọdá Jọ́dánì,+ tí ẹ sì wá ń gbé ní ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kó di tiyín, ó dájú pé ó máa mú kí ẹ sinmi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá yín tó yí yín ká, ẹ ó sì máa gbé láìséwu.+

  • Jóṣúà 1:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “Ẹ rántí ohun tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà pa láṣẹ fún yín pé:+ ‘Jèhófà Ọlọ́run yín máa fún yín ní ìsinmi, ó sì ti fún yín ní ilẹ̀ yìí.

  • Jóṣúà 11:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jóṣúà wá gba gbogbo ilẹ̀ náà, bí Jèhófà ṣe ṣèlérí fún Mósè,+ Jóṣúà sì fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì, bí ìpín wọn, pé kí wọ́n pín in láàárín àwọn ẹ̀yà wọn.+ Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+

  • Jóṣúà 22:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jèhófà Ọlọ́run yín ti wá fún àwọn arákùnrin yín ní ìsinmi, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+ Torí náà, ẹ lè pa dà sí àgọ́ yín ní ilẹ̀ tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún yín pé kí ẹ jogún ní òdìkejì* Jọ́dánì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́