2 Sámúẹ́lì 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Wọ́n tún bá àwọn Filísínì jà+ ní Góbù, Élíhánánì ọmọ Jaare-órégímù ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù sì pa Gòláyátì ará Gátì, ẹni tí igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ.*+
19 Wọ́n tún bá àwọn Filísínì jà+ ní Góbù, Élíhánánì ọmọ Jaare-órégímù ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù sì pa Gòláyátì ará Gátì, ẹni tí igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ.*+