2 Kíróníkà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní òpin ogún (20) ọdún tí Sólómọ́nì fi kọ́ ilé Jèhófà àti ilé ara rẹ̀,*+ 2 Kíróníkà 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó tún kọ́ Bẹti-hórónì Òkè+ àti Bẹti-hórónì Ìsàlẹ̀,+ àwọn ìlú aláàbò tó ní ògiri àti àwọn ẹnubodè pẹ̀lú ọ̀pá ìdábùú.
5 Ó tún kọ́ Bẹti-hórónì Òkè+ àti Bẹti-hórónì Ìsàlẹ̀,+ àwọn ìlú aláàbò tó ní ògiri àti àwọn ẹnubodè pẹ̀lú ọ̀pá ìdábùú.