1 Àwọn Ọba 6:37, 38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ní ọdún kẹrin, oṣù Sífì,* wọ́n fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà lélẹ̀;+ 38 ní ọdún kọkànlá, oṣù Búlì* (ìyẹn, oṣù kẹjọ), wọ́n parí gbogbo iṣẹ́ ilé náà bó ṣe wà nínú àwòrán ilé kíkọ́ rẹ̀.+ Torí náà, ọdún méje ni ó fi kọ́ ọ. 1 Àwọn Ọba 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọdún mẹ́tàlá (13) ló gba Sólómọ́nì láti kọ́ ilé* rẹ̀,+ títí ó fi parí ilé náà látòkèdélẹ̀.+ 1 Àwọn Ọba 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní òpin ogún (20) ọdún tí Sólómọ́nì fi kọ́ ilé méjèèjì, ìyẹn ilé Jèhófà àti ilé* ọba,+
37 Ní ọdún kẹrin, oṣù Sífì,* wọ́n fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà lélẹ̀;+ 38 ní ọdún kọkànlá, oṣù Búlì* (ìyẹn, oṣù kẹjọ), wọ́n parí gbogbo iṣẹ́ ilé náà bó ṣe wà nínú àwòrán ilé kíkọ́ rẹ̀.+ Torí náà, ọdún méje ni ó fi kọ́ ọ.