Jóṣúà 24:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Bákan náà, Élíásárì ọmọ Áárónì kú.+ Wọ́n sì sin ín sí Òkè Fíníhásì ọmọ rẹ̀,+ èyí tí wọ́n fún un ní agbègbè olókè Éfúrémù.
33 Bákan náà, Élíásárì ọmọ Áárónì kú.+ Wọ́n sì sin ín sí Òkè Fíníhásì ọmọ rẹ̀,+ èyí tí wọ́n fún un ní agbègbè olókè Éfúrémù.