Ẹ́kísódù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Élíásárì+ ọmọ Áárónì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Pútíélì ṣe aya. Ó bí Fíníhásì fún un.+ Àwọn ni olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+ Àwọn Onídàájọ́ 20:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Fíníhásì+ ọmọ Élíásárì, ọmọ Áárónì, ló ń ṣiṣẹ́* níwájú rẹ̀ nígbà yẹn. Wọ́n béèrè pé: “Ṣé ká tún lọ bá àwọn arákùnrin wa, àwọn ọkùnrin Bẹ́ńjámínì jà, àbí ká má lọ mọ́?”+ Jèhófà fèsì pé: “Ẹ lọ, torí ọ̀la ni màá fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.”
25 Élíásárì+ ọmọ Áárónì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Pútíélì ṣe aya. Ó bí Fíníhásì fún un.+ Àwọn ni olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+
28 Fíníhásì+ ọmọ Élíásárì, ọmọ Áárónì, ló ń ṣiṣẹ́* níwájú rẹ̀ nígbà yẹn. Wọ́n béèrè pé: “Ṣé ká tún lọ bá àwọn arákùnrin wa, àwọn ọkùnrin Bẹ́ńjámínì jà, àbí ká má lọ mọ́?”+ Jèhófà fèsì pé: “Ẹ lọ, torí ọ̀la ni màá fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.”