Jóṣúà 19:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kèké kẹrin+ mú Ísákà,+ àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà ní ìdílé-ìdílé. 18 Ààlà wọn dé Jésírẹ́lì,+ Kẹ́súlótì, Ṣúnémù,+ Àwọn Onídàájọ́ 6:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Gbogbo àwọn ọmọ Mídíánì,+ Ámálékì+ àti àwọn Ará Ìlà Oòrùn wá da àwọn ọmọ ogun wọn pọ̀;+ wọ́n sọdá* sí Àfonífojì* Jésírẹ́lì, wọ́n sì pàgọ́.
17 Kèké kẹrin+ mú Ísákà,+ àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà ní ìdílé-ìdílé. 18 Ààlà wọn dé Jésírẹ́lì,+ Kẹ́súlótì, Ṣúnémù,+
33 Gbogbo àwọn ọmọ Mídíánì,+ Ámálékì+ àti àwọn Ará Ìlà Oòrùn wá da àwọn ọmọ ogun wọn pọ̀;+ wọ́n sọdá* sí Àfonífojì* Jésírẹ́lì, wọ́n sì pàgọ́.