1 Sámúẹ́lì 28:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn Filísínì kóra jọ, wọ́n lọ, wọ́n sì pabùdó sí Ṣúnémù.+ Nítorí náà, Sọ́ọ̀lù kó gbogbo Ísírẹ́lì jọ, wọ́n sì pabùdó sí Gíbóà.+ 1 Àwọn Ọba 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n wá ọmọbìnrin tó rẹwà kiri gbogbo ilẹ̀ Ísírẹ́lì, wọ́n rí Ábíṣágì+ ará Ṣúnémù,+ wọ́n sì mú un wá fún ọba. 2 Àwọn Ọba 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lọ́jọ́ kan, Èlíṣà lọ sí Ṣúnémù,+ níbi tí gbajúmọ̀ obìnrin kan wà, obìnrin náà sì rọ̀ ọ́ pé kó jẹun níbẹ̀.+ Nígbàkigbà tó bá kọjá, ó máa ń dúró jẹun níbẹ̀.
4 Àwọn Filísínì kóra jọ, wọ́n lọ, wọ́n sì pabùdó sí Ṣúnémù.+ Nítorí náà, Sọ́ọ̀lù kó gbogbo Ísírẹ́lì jọ, wọ́n sì pabùdó sí Gíbóà.+
3 Wọ́n wá ọmọbìnrin tó rẹwà kiri gbogbo ilẹ̀ Ísírẹ́lì, wọ́n rí Ábíṣágì+ ará Ṣúnémù,+ wọ́n sì mú un wá fún ọba.
8 Lọ́jọ́ kan, Èlíṣà lọ sí Ṣúnémù,+ níbi tí gbajúmọ̀ obìnrin kan wà, obìnrin náà sì rọ̀ ọ́ pé kó jẹun níbẹ̀.+ Nígbàkigbà tó bá kọjá, ó máa ń dúró jẹun níbẹ̀.