-
Jóṣúà 3:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Jóṣúà sì sọ fún àwọn àlùfáà pé: “Ẹ gbé àpótí+ májẹ̀mú náà, kí ẹ máa nìṣó níwájú àwọn èèyàn náà.” Torí náà, wọ́n gbé àpótí májẹ̀mú, wọ́n sì ń lọ níwájú àwọn èèyàn náà.
-
-
Ìṣe 7:44, 45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 “Àwọn baba ńlá wa ní àgọ́ ẹ̀rí nínú aginjù, bí Ọlọ́run ṣe pa á láṣẹ nígbà tó sọ fún Mósè pé kó ṣe é bí èyí tí ó rí.+ 45 Àwọn baba ńlá wa jogún rẹ̀, wọ́n sì gbé e wá nígbà tí wọ́n ń tẹ̀ lé Jóṣúà bọ̀ ní ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+ àwọn tí Ọlọ́run lé jáde kúrò níwájú àwọn baba ńlá wa.+ Ó sì wà níbẹ̀ títí di ìgbà ayé Dáfídì.
-