Jóṣúà 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n pààlà náà látorí òkè dé ibi ìsun omi Néfítóà,+ ó sì lọ dé àwọn ìlú Òkè Éfúrónì; wọ́n tún pààlà dé Báálà, ìyẹn Kiriati-jéárímù.+
9 Wọ́n pààlà náà látorí òkè dé ibi ìsun omi Néfítóà,+ ó sì lọ dé àwọn ìlú Òkè Éfúrónì; wọ́n tún pààlà dé Báálà, ìyẹn Kiriati-jéárímù.+