-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
1 Kíróníkà 4:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Ibi tí wọ́n tẹ̀ dó sí ni Étámì, Áyínì, Rímónì, Tókénì àti Áṣánì,+ ìlú márùn-ún,
-
-
1 Kíróníkà 6:64Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
64 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú yìí pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko+ wọn nìyẹn.
-