Àwọn Onídàájọ́ 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Júdà wá sọ fún Síméónì ẹ̀gbọ́n rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká jọ lọ sí ilẹ̀ tí wọ́n fún mi,*+ ká lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì jà. Èmi náà á sì bá ọ lọ sí ilẹ̀ tí wọ́n fún ọ.” Torí náà, Síméónì tẹ̀ lé e lọ.
3 Júdà wá sọ fún Síméónì ẹ̀gbọ́n rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká jọ lọ sí ilẹ̀ tí wọ́n fún mi,*+ ká lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì jà. Èmi náà á sì bá ọ lọ sí ilẹ̀ tí wọ́n fún ọ.” Torí náà, Síméónì tẹ̀ lé e lọ.