Jóṣúà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù. Jóṣúà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kèké kejì+ wá mú Síméónì, ẹ̀yà Síméónì+ ní ìdílé-ìdílé. Ogún wọn sì wà láàárín ogún Júdà.+ Jóṣúà 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Inú ìpín Júdà ni wọ́n ti mú ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì, torí pé ìpín Júdà ti pọ̀ jù fún wọn. Torí náà, àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì gba ohun ìní tiwọn láàárín ogún wọn.+
15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù.
9 Inú ìpín Júdà ni wọ́n ti mú ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì, torí pé ìpín Júdà ti pọ̀ jù fún wọn. Torí náà, àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì gba ohun ìní tiwọn láàárín ogún wọn.+