Jóṣúà 19:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kèké kẹrin+ mú Ísákà,+ àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà ní ìdílé-ìdílé. 18 Ààlà wọn dé Jésírẹ́lì,+ Kẹ́súlótì, Ṣúnémù,+ 2 Àwọn Ọba 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lọ́jọ́ kan, Èlíṣà lọ sí Ṣúnémù,+ níbi tí gbajúmọ̀ obìnrin kan wà, obìnrin náà sì rọ̀ ọ́ pé kó jẹun níbẹ̀.+ Nígbàkigbà tó bá kọjá, ó máa ń dúró jẹun níbẹ̀.
17 Kèké kẹrin+ mú Ísákà,+ àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà ní ìdílé-ìdílé. 18 Ààlà wọn dé Jésírẹ́lì,+ Kẹ́súlótì, Ṣúnémù,+
8 Lọ́jọ́ kan, Èlíṣà lọ sí Ṣúnémù,+ níbi tí gbajúmọ̀ obìnrin kan wà, obìnrin náà sì rọ̀ ọ́ pé kó jẹun níbẹ̀.+ Nígbàkigbà tó bá kọjá, ó máa ń dúró jẹun níbẹ̀.