-
1 Kíróníkà 6:54-56Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
54 Bí a ṣe ṣètò wọn sí ibùdó wọn* ní ìpínlẹ̀ tí wọ́n ń gbé nìyí: fún àwọn ọmọ Áárónì tí wọ́n jẹ́ ti ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì, nítorí ọwọ́ wọn ni ìpín àkọ́kọ́ bọ́ sí, 55 wọ́n fún wọn ní Hébúrónì+ ní ilẹ̀ Júdà pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko tó yí i ká. 56 Àmọ́ Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè ni wọ́n fún ní pápá tó wà ní ìlú náà àti àwọn ìletò rẹ̀.
-