ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 10:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Lọ́jọ́ tí Jèhófà ṣẹ́gun àwọn Ámórì níṣojú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ìgbà yẹn ni Jóṣúà sọ fún Jèhófà níṣojú Ísírẹ́lì pé:

      “Oòrùn, dúró sójú kan+ lórí Gíbíónì,+

      Àti òṣùpá, lórí Àfonífojì* Áíjálónì!”

  • Àwọn Onídàájọ́ 1:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Torí náà, àwọn Ámórì ṣì ń gbé ní Òkè Hérésì, Áíjálónì+ àti Ṣáálíbímù.+ Àmọ́ nígbà tí agbára* ilé Jósẹ́fù pọ̀ sí i,* wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.

  • 2 Kíróníkà 28:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Àwọn Filísínì+ náà tún wá kó ẹrù àwọn èèyàn ní àwọn ìlú Ṣẹ́fẹ́là+ àti Négébù ti Júdà, wọ́n sì gba Bẹti-ṣémẹ́ṣì,+ Áíjálónì,+ Gédérótì, Sókò àti àwọn àrọko rẹ̀,* Tímúnà+ àti àwọn àrọko rẹ̀ pẹ̀lú Gímúsò àti àwọn àrọko rẹ̀; wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé níbẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́