Jóṣúà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ohun tí kò tọ́ nípa ohun tí wọ́n máa pa run, torí Ákánì+ ọmọ Kámì, ọmọ Sábídì, ọmọ Síírà látinú ẹ̀yà Júdà kó lára àwọn ohun tí wọ́n máa pa run.+ Ìyẹn mú kí Jèhófà bínú gidigidi sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 1 Kíróníkà 21:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà náà, Jèhófà rán àjàkálẹ̀ àrùn+ sí Ísírẹ́lì, tó fi jẹ́ pé ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) èèyàn lára Ísírẹ́lì kú.+
7 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ohun tí kò tọ́ nípa ohun tí wọ́n máa pa run, torí Ákánì+ ọmọ Kámì, ọmọ Sábídì, ọmọ Síírà látinú ẹ̀yà Júdà kó lára àwọn ohun tí wọ́n máa pa run.+ Ìyẹn mú kí Jèhófà bínú gidigidi sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
14 Nígbà náà, Jèhófà rán àjàkálẹ̀ àrùn+ sí Ísírẹ́lì, tó fi jẹ́ pé ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) èèyàn lára Ísírẹ́lì kú.+