7 Torí náà, kí wọ́n má ṣe rú ẹbọ mọ́ sí àwọn ẹ̀mí èṣù tó rí bí ewúrẹ́,*+ èyí tí wọ́n ń bá ṣèṣekúṣe.+ Kí èyí jẹ́ àṣẹ tó máa wà títí lọ fún yín, jálẹ̀ àwọn ìran yín.”’
8 Kò jáwọ́ nínú iṣẹ́ aṣẹ́wó tó ṣe ní Íjíbítì, torí wọ́n ti bá a sùn nígbà èwe rẹ̀, wọ́n fọwọ́ pa á láyà nígbà tí kò tíì mọ ọkùnrin, wọ́n sì tẹ́ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ wọn lọ́rùn lára rẹ̀.*+