Rúùtù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 ṣé ẹ máa wá dúró títí wọ́n á fi dàgbà? Ṣé ẹ ò wá ní lọ́kọ nítorí wọn ni? Rárá o, ẹ̀yin ọmọ mi, ohun tó ṣẹlẹ̀ sí yín bà mí nínú jẹ́ gan-an torí Jèhófà ti bínú sí mi.”+
13 ṣé ẹ máa wá dúró títí wọ́n á fi dàgbà? Ṣé ẹ ò wá ní lọ́kọ nítorí wọn ni? Rárá o, ẹ̀yin ọmọ mi, ohun tó ṣẹlẹ̀ sí yín bà mí nínú jẹ́ gan-an torí Jèhófà ti bínú sí mi.”+