Rúùtù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó sì ń fèsì pé: “Ẹ má pè mí ní Náómì* mọ́. Márà* ni kí ẹ máa pè mí, torí Olódùmarè ti mú kí ayé mi korò gan-an.+
20 Ó sì ń fèsì pé: “Ẹ má pè mí ní Náómì* mọ́. Márà* ni kí ẹ máa pè mí, torí Olódùmarè ti mú kí ayé mi korò gan-an.+