ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Rúùtù 4:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Torí náà, gbogbo àwọn tó wà ní ẹnubodè ìlú àti àwọn àgbààgbà sọ pé: “Àwa jẹ́rìí sí i! Kí Jèhófà jẹ́ kí ìyàwó tó máa tó wọ ilé rẹ dà bíi Réṣẹ́lì àti Líà, àwọn méjì tó kọ́ ilé Ísírẹ́lì.+ Kí nǹkan máa lọ dáadáa fún ọ ní Éfúrátà,+ kí o sì ní orúkọ rere* ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.+

  • Rúùtù 4:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ìgbà náà ni àwọn obìnrin tó wà ládùúgbò fún ọmọ náà ní orúkọ. Wọ́n sọ pé, “Náómì ti ní ọmọkùnrin kan.” Wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Óbédì.+ Òun ló wá bí Jésè,+ bàbá Dáfídì.

  • Mátíù 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;

      Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+

      Óbédì bí Jésè;+

  • Mátíù 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Jékọ́bù bí Jósẹ́fù ọkọ Màríà, ẹni tó bí Jésù,+ tí à ń pè ní Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́