Sáàmù 17:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Dáàbò bò mí bí ọmọlójú rẹ;+Fi mí pa mọ́ sábẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.+ Sáàmù 36:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+ Sáàmù 57:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+ Sáàmù 63:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi,+Mo sì ń kígbe ayọ̀ lábẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.+
7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+
57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+