Rúùtù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí Jèhófà san ẹ̀san ohun tí o ṣe fún ọ,+ kí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí o wá ààbò wá sábẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀+ sì fún ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ èrè.” Sáàmù 36:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+ Sáàmù 57:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+
12 Kí Jèhófà san ẹ̀san ohun tí o ṣe fún ọ,+ kí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí o wá ààbò wá sábẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀+ sì fún ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ èrè.”
7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+
57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+