-
Rúùtù 2:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Mọ̀lẹ́bí ọkọ Náómì kan wà tó ní ọrọ̀ gan-an, Bóásì+ ni orúkọ rẹ̀, ìdílé Élímélékì ló sì ti wá.