4 Torí náà, mo rò pé ó yẹ kí n sọ fún ọ nípa rẹ̀ pé, ‘Rà á níṣojú àwọn ará ìlú àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn mi.+ Tí o bá máa tún un rà, tún un rà. Ṣùgbọ́n tí o kò bá ní tún un rà, jọ̀ọ́ sọ fún mi, kí n lè mọ̀, torí ìwọ lo lẹ́tọ̀ọ́ láti tún un rà, èmi ló sì tẹ̀ lé ọ.’” Ó dáhùn pé: “Màá tún un rà.”+