-
1 Sámúẹ́lì 2:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Bí mo ti ń ṣe rere fún Ísírẹ́lì, alátakò ni wàá máa rí nínú ibùgbé mi,+ kò tún ní sí ẹni tó máa dàgbà nínú ilé rẹ mọ́ láé.
-
-
1 Sámúẹ́lì 2:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọkùnrin rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì yóò jẹ́ àmì fún ọ: Ọjọ́ kan náà ni àwọn méjèèjì máa kú.+
-
-
1 Sámúẹ́lì 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Gbàrà tí àpótí májẹ̀mú Jèhófà dé sí ibùdó, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì hó yèè, tí ilẹ̀ fi mì tìtì.
-
-
1 Sámúẹ́lì 4:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n gba Àpótí Ọlọ́run, àwọn ọmọ Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì sì kú.+
-