-
1 Sámúẹ́lì 2:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọkùnrin rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì yóò jẹ́ àmì fún ọ: Ọjọ́ kan náà ni àwọn méjèèjì máa kú.+
-
-
Sáàmù 78:61Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
61 Ó jẹ́ kí àmì agbára rẹ̀ lọ sóko ẹrú;
Ó jẹ́ kí ọlá ńlá rẹ̀ bọ́ sọ́wọ́ àwọn ọ̀tá.+
-