-
1 Sámúẹ́lì 4:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n gba Àpótí Ọlọ́run, àwọn ọmọ Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì sì kú.+
-
-
1 Sámúẹ́lì 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà tí àwọn Filísínì gba Àpótí+ Ọlọ́run tòótọ́, wọ́n gbé e láti Ẹbinísà wá sí Áṣídódì.
-
-
Sáàmù 78:61Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
61 Ó jẹ́ kí àmì agbára rẹ̀ lọ sóko ẹrú;
Ó jẹ́ kí ọlá ńlá rẹ̀ bọ́ sọ́wọ́ àwọn ọ̀tá.+
-