-
1 Sámúẹ́lì 6:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ẹ gbé Àpótí Jèhófà sórí kẹ̀kẹ́ náà, kí ẹ sì kó àwọn ère wúrà tí ẹ fẹ́ fi ránṣẹ́ sí i gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹ̀bi sínú àpótí tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.+ Kí ẹ wá rán an lọ, 9 kí ẹ sì máa wò ó: Tó bá jẹ́ pé ọ̀nà Bẹti-ṣémẹ́ṣì+ ló lọ, ní ìpínlẹ̀ rẹ̀, á jẹ́ pé Ọlọ́run wọn ló fa ibi ńlá tó bá wa yìí. Àmọ́ tí kò bá rí bẹ́ẹ̀, a ó mọ̀ pé kì í ṣe ọwọ́ rẹ̀ ló kọ lù wá; ó kàn ṣèèṣì wáyé bẹ́ẹ̀ ni.”
-