1 Sámúẹ́lì 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àfi kí ẹ bẹ̀rù Jèhófà,+ kí ẹ sì fi gbogbo ọkàn yín sìn ín ní òdodo,* ẹ̀yin náà ẹ wo àwọn ohun ńlá tí ó ti ṣe fún yín.+
24 Àfi kí ẹ bẹ̀rù Jèhófà,+ kí ẹ sì fi gbogbo ọkàn yín sìn ín ní òdodo,* ẹ̀yin náà ẹ wo àwọn ohun ńlá tí ó ti ṣe fún yín.+