Ẹ́kísódù 20:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Tí o bá fi òkúta ṣe pẹpẹ fún mi, o ò gbọ́dọ̀ lo òkúta tí o fi irinṣẹ́ gbẹ́.*+ Torí tí o bá lo irinṣẹ́* rẹ lára rẹ̀, wàá sọ ọ́ di aláìmọ́.
25 Tí o bá fi òkúta ṣe pẹpẹ fún mi, o ò gbọ́dọ̀ lo òkúta tí o fi irinṣẹ́ gbẹ́.*+ Torí tí o bá lo irinṣẹ́* rẹ lára rẹ̀, wàá sọ ọ́ di aláìmọ́.