ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 17:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Tí o bá dé ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ, tí o gbà á, tí o ti ń gbé ibẹ̀, tí o wá sọ pé, ‘Jẹ́ kí n yan ọba lé ara mi lórí, bíi ti àwọn orílẹ̀-èdè tó yí mi ká,’+ 15 nígbà náà, kí o rí i dájú pé ẹni tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá yàn ni kí o fi jọba.+ Àárín àwọn arákùnrin rẹ ni kí o ti yan ẹni tó máa jọba. O ò gbọ́dọ̀ yan àjèjì, ẹni tí kì í ṣe arákùnrin rẹ ṣe olórí rẹ.

  • 1 Sámúẹ́lì 12:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọba tí ẹ fẹ́ nìyí, ẹni tí ẹ béèrè. Ẹ wò ó! Jèhófà ti fi ọba jẹ lórí yín.+

  • Ìṣe 13:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àmọ́ nígbà tó yá, wọ́n ní àwọn fẹ́ ọba,+ Ọlọ́run sì fún wọn ní Sọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì,+ ó fi ogójì (40) ọdún jọba.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́