ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 8:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Àmọ́ Gídíónì sọ fún wọn pé: “Mi ò ní jọba lé yín lórí, ọmọ mi náà ò sì ní jọba lé yín lórí. Jèhófà ló máa jọba lé yín lórí.”+

  • 1 Sámúẹ́lì 10:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́ lónìí, ẹ ti kọ Ọlọ́run yín+ tó jẹ́ Olùgbàlà yín, tó gbà yín lọ́wọ́ gbogbo ibi àti wàhálà tó bá yín, ẹ sì sọ pé: “Àní sẹ́, fi ọba jẹ lórí wa.” Ní báyìí, ẹ dúró níwájú Jèhófà ní ẹ̀yà-ẹ̀yà àti ní ẹgbẹ̀rún-ẹgbẹ̀rún.’”*

  • 1 Sámúẹ́lì 12:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Nígbà tí ẹ rí i pé Náháṣì+ ọba àwọn ọmọ Ámónì ti wá gbéjà kò yín, léraléra lẹ sọ fún mi pé, ‘Àní sẹ́, a ti pinnu láti ní ọba tiwa!’+ bó tilẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà Ọlọ́run yín ni Ọba yín.+

  • Àìsáyà 33:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+

      Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+

      Jèhófà ni Ọba wa;+

      Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́