-
1 Sámúẹ́lì 10:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Tí o bá ti kúrò lọ́dọ̀ mi lónìí, wàá rí ọkùnrin méjì nítòsí ibojì Réṣẹ́lì+ ní ìpínlẹ̀ Bẹ́ńjámínì tó wà ní Sélésà, wọ́n á sì sọ fún ọ pé, ‘A ti rí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí o wá lọ, bàbá rẹ kò tiẹ̀ ronú nípa àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà+ mọ́, àmọ́ ní báyìí ó ti ń dààmú nípa yín. Ó sọ pé: “Kí ni màá ṣe nípa ọmọ mi?”’
-