-
1 Sámúẹ́lì 9:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* Kíṣì bàbá Sọ́ọ̀lù sọ nù, Kíṣì sọ fún Sọ́ọ̀lù ọmọ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, mú ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ dání, kí o sì lọ wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.”
-
-
1 Sámúẹ́lì 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Wọ́n dé ilẹ̀ Súfì, Sọ́ọ̀lù wá sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀ tó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Wá, jẹ́ ká pa dà, kí bàbá mi má bàa bẹ̀rẹ̀ sí í dààmú nípa wa dípò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.”+
-